Ìfihàn 4:5 BM

5 Mànàmáná ati ìró ààrá ń jáde láti ara ìtẹ́ tí ó wà láàrin. Ògùṣọ̀ meje tí iná wọn ń jó wà níwájú ìtẹ́ náà. Àwọn yìí ni Ẹ̀mí Ọlọrun meje.

Ka pipe ipin Ìfihàn 4

Wo Ìfihàn 4:5 ni o tọ