Ìfihàn 8:1 BM

1 Nígbà tí Ọ̀dọ́ Aguntan náà tú èdìdì keje, gbogbo ohun tí ó wà ní ọ̀run parọ́rọ́ fún bí ìdajì wakati kan.

Ka pipe ipin Ìfihàn 8

Wo Ìfihàn 8:1 ni o tọ