Ìfihàn 7:17 BM

17 Nítorí Ọ̀dọ́ Aguntan tí ó wà láàrin ìtẹ́ náà ni yóo máa ṣe olùtọ́jú wọn, yóo máa dà wọ́n lọ síbi ìsun omi ìyè.Ọlọrun yóo wá nu gbogbo omijé kúrò ní ojú wọn.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 7

Wo Ìfihàn 7:17 ni o tọ