Ìfihàn 8:9 BM

9 Ìdámẹ́ta gbogbo ohun ẹlẹ́mìí tí ó wà ninu òkun ni wọ́n kú. Ìdámẹ́ta àwọn ọkọ̀ ojú òkun ni wọ́n sì fọ́ túútúú.

Ka pipe ipin Ìfihàn 8

Wo Ìfihàn 8:9 ni o tọ