Ìfihàn 9:6 BM

6 Ní ọjọ́ náà àwọn eniyan yóo máa wá ikú ṣugbọn wọn kò ní kú; wọn yóo tọrọ ikú, ṣugbọn kò ní súnmọ́ wọn.

Ka pipe ipin Ìfihàn 9

Wo Ìfihàn 9:6 ni o tọ