Ìfihàn 9:7 BM

7 Àwọn eṣú wọnyi dàbí àwọn ẹṣin tí a dì ní gàárì láti lọ sójú ogun. Adé wà ní orí wọn tí ó dàbí adé wúrà. Ojú wọn dàbí ojú eniyan.

Ka pipe ipin Ìfihàn 9

Wo Ìfihàn 9:7 ni o tọ