Kọrinti Keji 1:21 BM

21 Ọlọrun ni ó fún àwa ati ẹ̀yin ní ìdánilójú pé a wà ninu Kristi, òun ni ó ti fi òróró yàn wá.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 1

Wo Kọrinti Keji 1:21 ni o tọ