Kọrinti Keji 1:22 BM

22 Ó ti fi èdìdì rẹ̀ sí wa lára, ó tún fi Ẹ̀mí Mímọ́ ṣe onídùúró sí ọkàn wa gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rí ohun tí yóo tún fún wa.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 1

Wo Kọrinti Keji 1:22 ni o tọ