23 Mo fi Ọlọrun jẹ́rìí ohun tí n óo sọ yìí. Mo sì fi ẹ̀mí mi búra! Ìdí tí n kò fi wá sí Kọrinti mọ́ ni pé n kò fẹ́ yọ yín lẹ́nu.
Ka pipe ipin Kọrinti Keji 1
Wo Kọrinti Keji 1:23 ni o tọ