Kọrinti Keji 3:7 BM

7 Bí òfin tí a kọ sí ara òkúta tí ó jẹ́ iranṣẹ ikú bá wá pẹlu ògo, tóbẹ́ẹ̀ tí àwọn ọmọ Israẹli kò lè ṣíjú wo Mose, nítorí ìmọ́lẹ̀ tí ń tàn ní ojú rẹ̀ fún àkókò díẹ̀,

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 3

Wo Kọrinti Keji 3:7 ni o tọ