Kọrinti Keji 5:19 BM

19 Iṣẹ́ náà ni pé Ọlọrun wà ninu Kristi, ó ń làjà láàrin aráyé ati ara rẹ̀. Kò ka àwọn ìwà àìṣedéédé wọn sí wọn lọ́rùn. Ó sì ti wá fi ọ̀rọ̀ ìlàjà lé wa lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 5

Wo Kọrinti Keji 5:19 ni o tọ