20 Nítorí náà, a jẹ́ aṣojú fún Kristi. Ó dàbí ẹni pé àwa ni Ọlọrun ń lò láti fi bẹ̀ yín. A fi orúkọ Kristi bẹ̀ yín, ẹ bá Ọlọrun rẹ́.
Ka pipe ipin Kọrinti Keji 5
Wo Kọrinti Keji 5:20 ni o tọ