Kọrinti Keji 8:18 BM

18 A rán arakunrin tí ó lókìkí ninu gbogbo àwọn ìjọ nítorí iṣẹ́ rẹ̀ nípa ìyìn rere pé kí ó bá a wá.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 8

Wo Kọrinti Keji 8:18 ni o tọ