Kọrinti Keji 8:19 BM

19 Kì í ṣe pé ó lókìkí nìkan ni, ṣugbọn òun ni ẹni tí gbogbo àwọn ìjọ yàn pé kí ó máa bá wa kiri nípa iṣẹ́ oore-ọ̀fẹ́ tí à ń ṣe fún ògo Oluwa ati láti fi ìtara wa hàn.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 8

Wo Kọrinti Keji 8:19 ni o tọ