Kọrinti Keji 8:20 BM

20 À ń ṣe èyí kí ẹnikẹ́ni má baà rí nǹkan wí sí wa nípa ọ̀nà tí à ń gbà ṣe ètò ti ẹ̀bùn yìí.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 8

Wo Kọrinti Keji 8:20 ni o tọ