Kọrinti Keji 8:22 BM

22 A tún rán arakunrin wa tí a ti dánwò ní oríṣìíríṣìí ọ̀nà ní ti ìtara rẹ̀ pé kí ó bá wọn wá. Nisinsinyii ó túbọ̀ ní ìtara pupọ nítorí ó gbẹ́kẹ̀lé yín pupọ.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 8

Wo Kọrinti Keji 8:22 ni o tọ