Kọrinti Keji 8:23 BM

23 Ní ti Titu, ẹlẹgbẹ́ mi ati alábàáṣiṣẹ́ mi ni ninu ohun tí ó kàn yín. Ní ti àwọn arakunrin wa, òjíṣẹ́ àwọn ìjọ ni wọ́n, Ògo Kristi sì ni wọ́n.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 8

Wo Kọrinti Keji 8:23 ni o tọ