Matiu 10:26 BM

26 “Nítorí náà, ẹ má bẹ̀rù àwọn eniyan. Kò sí ohun tí ó wà ní ìpamọ́, tí kò ní fara hàn. Kò sì sí ohun àṣírí tí a kò ní mọ̀.

Ka pipe ipin Matiu 10

Wo Matiu 10:26 ni o tọ