Matiu 11:10 BM

10 Òun ni àkọsílẹ̀ wà nípa rẹ̀ pé: ‘Wò ó! Mo rán oníṣẹ́ mi ṣiwaju rẹ òun ni yóo palẹ̀ mọ́ dè ọ́.’

Ka pipe ipin Matiu 11

Wo Matiu 11:10 ni o tọ