Matiu 12:11 BM

11 Ó bá bi wọ́n báyìí pé, “Ta ni ninu yín tí yóo ní aguntan kan, bí ọ̀kan náà bá jìn sí kòtò ní Ọjọ́ Ìsinmi, tí kò ní fà á jáde?

Ka pipe ipin Matiu 12

Wo Matiu 12:11 ni o tọ