Matiu 12:2 BM

2 Nígbà tí àwọn Farisi rí i, wọ́n wí fún un pé, “Wò ó! Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ ń ṣe ohun tí kò tọ́ láti ṣe ní Ọjọ́ Ìsinmi.”

Ka pipe ipin Matiu 12

Wo Matiu 12:2 ni o tọ