Matiu 13:22 BM

22 Ti ààrin igi ẹlẹ́gùn-ún ni ẹni tí ó gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, tí àníyàn ayé yìí ati ìtànjẹ ọrọ̀ fún ọ̀rọ̀ náà pa, tí kò fi so èso.

Ka pipe ipin Matiu 13

Wo Matiu 13:22 ni o tọ