Matiu 13:35 BM

35 kí ọ̀rọ̀ tí wolii ti sọ lè ṣẹ, nígbà tí ó sọ pé,“Bí òwe bí òwe ni ọ̀rọ̀ mi yóo jẹ́.N óo sọ àwọn ohun tí ó ti wà ní àṣírí láti ìpilẹ̀ṣẹ̀ ayé.”

Ka pipe ipin Matiu 13

Wo Matiu 13:35 ni o tọ