Matiu 13:38 BM

38 Ayé ni oko tí ó fúnrúgbìn sí. Irúgbìn rere ni àwọn ọmọ ìjọba ọ̀run. Èpò ni àwọn ọmọ èṣù.

Ka pipe ipin Matiu 13

Wo Matiu 13:38 ni o tọ