Matiu 14:12 BM

12 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Johanu bá wá, wọ́n gbé òkú rẹ̀ lọ, wọ́n sin ín; wọ́n sì lọ ròyìn fún Jesu.

Ka pipe ipin Matiu 14

Wo Matiu 14:12 ni o tọ