Matiu 14:36 BM

36 Wọ́n ń bẹ̀ ẹ́ pé kí wọn sá lè fi ọwọ́ kan etí ẹ̀wù rẹ̀. Gbogbo àwọn tí wọ́n fi ọwọ́ kàn án ni ó mú lára dá.

Ka pipe ipin Matiu 14

Wo Matiu 14:36 ni o tọ