Matiu 16:9 BM

9 Òye kò ì tíì ye yín sibẹ? Ẹ kò ranti burẹdi marun-un tí mo fi bọ́ ẹgbẹẹdọgbọn (5,000) eniyan ati iye agbọ̀n àjẹkù tí ẹ kó jọ?

Ka pipe ipin Matiu 16

Wo Matiu 16:9 ni o tọ