Matiu 17:19 BM

19 Nígbà tí ó yá àwọn ọmọ-ẹ̀yìn wá sọ́dọ̀ Jesu níkọ̀kọ̀, wọn bi í pé, “Kí ló dé tí àwa kò fi lè lé ẹ̀mí èṣù náà jáde?”

Ka pipe ipin Matiu 17

Wo Matiu 17:19 ni o tọ