Matiu 18:1 BM

1 Ní àkókò náà àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu wá sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n bi í pé, “Ta ní ṣe pataki jùlọ ní ìjọba ọ̀run?”

Ka pipe ipin Matiu 18

Wo Matiu 18:1 ni o tọ