Matiu 18:32 BM

32 Olówó ẹrú náà bá pè é, ó sọ fún un pé, ‘Ìwọ ẹrú burúkú yìí! Mo bùn ọ́ ní adúrú gbèsè nnì nítorí o bẹ̀ mí.

Ka pipe ipin Matiu 18

Wo Matiu 18:32 ni o tọ