Matiu 19:14 BM

14 Ṣugbọn Jesu sọ pé, “Ẹ jẹ́ kí àwọn ọmọde wá sọ́dọ̀ mi; ẹ má dí wọn lọ́nà, nítorí ti irú wọn ni ìjọba ọ̀run.”

Ka pipe ipin Matiu 19

Wo Matiu 19:14 ni o tọ