Matiu 19:26 BM

26 Jesu wò wọ́n lójú, ó sọ fún wọn pé, “Èyí kò ṣeéṣe fún eniyan; ṣugbọn ohun gbogbo ni ó ṣeéṣe fún Ọlọrun.”

Ka pipe ipin Matiu 19

Wo Matiu 19:26 ni o tọ