Matiu 2:18 BM

18 “A gbọ́ ohùn kan ní Rama,ẹkún ati ọ̀fọ̀ gidi.Rakẹli ń sunkún nítorí àwọn ọmọ rẹ̀;ó kọ̀, kò gba ìpẹ̀,nítorí wọn kò sí mọ́.”

Ka pipe ipin Matiu 2

Wo Matiu 2:18 ni o tọ