Matiu 2:20 BM

20 Ó sọ fún un pé, “Dìde, gbé ọmọ náà ati ìyá rẹ́, kí o pada lọ sí ilẹ̀ Israẹli, nítorí àwọn tí wọ́n fẹ́ pa ọmọ náà ti kú.”

Ka pipe ipin Matiu 2

Wo Matiu 2:20 ni o tọ