Matiu 2:7 BM

7 Hẹrọdu bá pe àwọn amòye náà síkọ̀kọ̀, ó fọgbọ́n wádìí àkókò tí ìràwọ̀ náà yọ lọ́dọ̀ wọn.

Ka pipe ipin Matiu 2

Wo Matiu 2:7 ni o tọ