Matiu 20:12 BM

12 Wọ́n ní, ‘Wakati kan péré ni àwọn yìí tí wọ́n dé kẹ́yìn ṣe; o wá san iye kan náà fún àwa ati àwọn, àwa tí a ṣe iṣẹ́ àṣelàágùn ninu oòrùn gangan!’

Ka pipe ipin Matiu 20

Wo Matiu 20:12 ni o tọ