Matiu 20:2 BM

2 Lẹ́yìn tí ó ti gbà láti fún àwọn òṣìṣẹ́ náà ní owó fadaka kan fún iṣẹ́ ojúmọ́, ó ní kí wọ́n lọ ṣiṣẹ́ ninu ọgbà àjàrà òun.

Ka pipe ipin Matiu 20

Wo Matiu 20:2 ni o tọ