Matiu 20:6 BM

6 Nígbà tí ó jáde ní agogo marun-un ìrọ̀lẹ́, ó rí àwọn mìíràn tí wọn dúró, ó bi wọ́n pé, ‘Kí ló dé tí ẹ fi dúró láti àárọ̀ láìṣe nǹkankan?’

Ka pipe ipin Matiu 20

Wo Matiu 20:6 ni o tọ