Matiu 21:26 BM

26 Bí a bá sì wí pé, ‘Láti ọ̀dọ̀ eniyan ni,’ a bẹ̀rù àwọn eniyan, nítorí gbogbo eniyan gbà pé wolii tòótọ́ ni Johanu.”

Ka pipe ipin Matiu 21

Wo Matiu 21:26 ni o tọ