Matiu 22:18 BM

18 Ṣugbọn Jesu mọ èrò ibi tí ó wà lọ́kàn wọn. Ó ní, “Kí ló dé tí ẹ fi ń dẹ mí ẹ̀yin alárèékérekè yìí?

Ka pipe ipin Matiu 22

Wo Matiu 22:18 ni o tọ