Matiu 22:23 BM

23 Ní ọjọ́ náà, àwọn Sadusi kan wá sọ́dọ̀ rẹ̀. (Àwọn Sadusi ni wọ́n sọ pé kò sí ajinde.) Wọ́n bi í pé,

Ka pipe ipin Matiu 22

Wo Matiu 22:23 ni o tọ