Matiu 22:7 BM

7 Inú wá bí ọba náà, ó bá rán àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ kí wọ́n pa àwọn apànìyàn wọ̀n-ọn-nì run, kí wọ́n sì dáná sun ìlú wọn.

Ka pipe ipin Matiu 22

Wo Matiu 22:7 ni o tọ