Matiu 23:30 BM

30 Ẹ wá ń sọ pé, ‘Bí ó bá jẹ́ pé a wà ní ìgbà àwọn baba wa, àwa kò bá tí lọ́wọ́ ninu ikú àwọn wolii.’

Ka pipe ipin Matiu 23

Wo Matiu 23:30 ni o tọ