Matiu 24:21 BM

21 Nítorí ìpọ́njú yóo pọ̀ ní àkókò náà, irú èyí tí kò sí rí láti ìbẹ̀rẹ̀ ayé títí di ìsinsìnyìí; irú rẹ̀ kò sì tún ní sí mọ́.

Ka pipe ipin Matiu 24

Wo Matiu 24:21 ni o tọ