Matiu 24:31 BM

31 Yóo wá rán angẹli rẹ̀ pẹlu fèrè ńlá, wọn yóo kó àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ jọ láti igun mẹrẹẹrin ayé; àní láti ìkangun ọ̀run kan dé ìkangun keji.

Ka pipe ipin Matiu 24

Wo Matiu 24:31 ni o tọ