Matiu 24:33 BM

33 Bẹ́ẹ̀ gan-an ni, nígbà tí ẹ bá rí gbogbo nǹkan wọnyi, kí ẹ̀yin náà mọ̀ pé àkókò súnmọ́ tòsí, ó ti dé ẹnu ọ̀nà.

Ka pipe ipin Matiu 24

Wo Matiu 24:33 ni o tọ