Matiu 24:36 BM

36 “Kò sí ẹni tí ó mọ ọjọ́ náà ati wakati náà. Àwọn angẹli ọ̀run kò mọ̀ ọ́n; ọmọ pàápàá kò mọ̀ ọ́n, àfi Baba nìkan ni ó mọ̀ ọ́n.

Ka pipe ipin Matiu 24

Wo Matiu 24:36 ni o tọ