Matiu 24:39 BM

39 Wọn kò fura títí ìkún-omi fi dé, tí ó gba gbogbo wọn lọ. Bẹ́ẹ̀ ni àkókò dídé Ọmọ-Eniyan yóo rí.

Ka pipe ipin Matiu 24

Wo Matiu 24:39 ni o tọ