Matiu 24:44 BM

44 Nítorí náà, kí ẹ̀yin náà wà ní ìmúrasílẹ̀, nítorí ní wakati tí ẹ kò rò tẹ́lẹ̀ ni Ọmọ-Eniyan yóo dé.

Ka pipe ipin Matiu 24

Wo Matiu 24:44 ni o tọ