Matiu 25:1 BM

1 “Ní àkókò náà, ọ̀rọ̀ ìjọba ọ̀run yóo dàbí ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí àwọn wundia mẹ́wàá, tí wọn gbé àtùpà wọn láti jáde lọ pàdé ọkọ iyawo.

Ka pipe ipin Matiu 25

Wo Matiu 25:1 ni o tọ